Ni odun yii 2017

NI ODUN 2017 adura MI si o ni wipe:

🏾A* – Alaafia ni fun ọ.

🏾B* – Buburu kan ki yio
ṣsubú lu ọ.

🏾D* – Dugbẹdugbẹ
ibanujẹ ko ni ja le ọ
l'ori.

🏾E* – Ebi ò ni pa ọ nibi ti
ọdún ku si yi.

🏾E* – Ẹkún, asun'da ko ni jẹ
tirẹ.

🏾F* – Funfun aye rẹ ko ni
d'ibajẹ.

🏾G* – Gunnugun ki ku
l'ewe, wa d'agba
d'arugbo.

🏾GB* – Gbogbo idawole
rẹ a yọrí si rere.

🏾H* – Hausa, Yoruba, Ibo,
gbogbo ẹya ati
eniyan kaakiri
agbaye ni yio kọju
si ọ ṣe ọ loore.

🏾I* – Iwaju, iwaju l'ọpa ẹbiti
rẹ yio ma re si.

🏾J* – Jijade rẹ, wiwole rẹ,
ò ó nik'agbako.

🏾K* – Kukuru abi giga –
ìsorò ko ni jẹ tìrẹ.

🏾L* – Loniloni wa r'aanu
gba.

🏾M*- Mọnamọna ati àra
Ọlọ́run yóò tu àwọn
ọta rẹ ka.

🏾N* – Naira, Euro, Dollar,
Pound, Yen, Yuan,
gbogbo owo ati ọrọ
kaakiri agbaye pẹlu
ọmọ alalubarika ati
alaafia yóò mu ọ
l'ọrẹ, wọn o si fi ile
re ṣe ibugbe.

🏾O* – Ojurere ati aanu yio
ma tọ ọ lẹ́yìn ni ọjọ
aye rẹ̀ gbogbo.

🏾Ọ* – Ọjọ́ ọ̀la rẹ a dara.

🏾P* – Panpẹ aye ò ni mu ọ
t'ọmọtọmọ.

🏾R* – Rere ni agogo aye rẹ
yió ma lu n'igba
gbogbo.

🏾S* – Suuru pẹlu ìtẹ́lọ́rùn
ninu ọrọ at'alaafia
yi o ba ọ́ kalẹ.

🏾Ṣ* – Ṣugbọ́n ati àbáwọn
aye rẹ ti poora loni.

🏾T* – T'ọmọtọmọ, t'ẹbitẹbi,
t'iletile o ni d'ero ẹyin.

🏾U* A kii wátí U ti l'ede
Ekiti Ujẹ̀ṣà; a o ni fi ọ̀
ṣàwátí laarin awọn
ọniyan (eniyan).
Ulọsiwaju (ilọsiwaju),
ure (ire), ati ubukun
(ibunkun) yio jẹ́ tìrẹ.

🏾W* – Wa ri ba ti ṣe, wa
r'ọna gbe gba.

🏾Y* – Yara ibukun, ire, ati
ayo ailopin loo ma
ba ọ gbe titi ọjọ aye
rẹ……

_🏾AMIN, L'AṢẸ EDUMARE.*_

_*IRE O!*_

_🏳Ìwọ naa fi ranṣẹ si
awon olólùfẹ́ rẹ. Bẹe ni, o
le fi ránṣẹ si emi naa ti
moba wa lara àwọn
olólùfẹ́ rẹ._

Sent from my Blog http://ift.tt/1scst35

from Blogger http://ift.tt/2nTDQ6E

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s