Ni odun yii 2017 NI ODUN 2017 adura MI si o ni wipe: 🏾A* – Alaafia ni fun ọ. 🏾B* – Buburu kan ki yio ṣsubú lu ọ. 🏾D* – Dugbẹdugbẹ ibanujẹ ko ni ja le ọ l’ori. 🏾E* – Ebi ò ni pa ọ nibi ti ọdún ku si yi. 🏾E* – Ẹkún, asun’da ko ni jẹ tirẹ. 🏾F* – Funfun aye rẹ ko ni d’ibajẹ. 🏾G* – Gunnugun ki ku l’ewe, wa d’agba d’arugbo. 🏾GB* – Gbogbo idawole rẹ a yọrí si rere. 🏾H* – Hausa, Yoruba, Ibo, gbogbo ẹya ati eniyan kaakiri agbaye ni yio kọju si ọ ṣe ọ loore. 🏾I* – Iwaju, iwaju l’ọpa ẹbiti rẹ yio ma re si. 🏾J* – Jijade rẹ, wiwole rẹ, ò ó nik’agbako. 🏾K* – Kukuru abi giga – ìsorò ko ni jẹ tìrẹ. 🏾L* – Loniloni wa r’aanu gba. 🏾M*- Mọnamọna ati àra Ọlọ́run yóò tu àwọn ọta rẹ ka. 🏾N* – Naira, Euro, Dollar, Pound, Yen, Yuan, gbogbo owo ati ọrọ kaakiri agbaye pẹlu ọmọ alalubarika ati alaafia yóò mu ọ l’ọrẹ, wọn o si fi ile re ṣe ibugbe. 🏾O* – Ojurere ati aanu yio ma tọ ọ lẹ́yìn ni ọjọ aye rẹ̀ gbogbo. 🏾Ọ* – Ọjọ́ ọ̀la rẹ a dara. 🏾P* – Panpẹ aye ò ni mu ọ t’ọmọtọmọ. 🏾R* – Rere ni agogo aye rẹ yió ma lu n’igba gbogbo. 🏾S* – Suuru pẹlu ìtẹ́lọ́rùn ninu ọrọ at’alaafia yi o ba ọ́ kalẹ. 🏾Ṣ* – Ṣugbọ́n ati àbáwọn aye rẹ ti poora loni. 🏾T* – T’ọmọtọmọ, t’ẹbitẹbi, t’iletile o ni d’ero ẹyin. 🏾U* A kii wátí U ti l’ede Ekiti Ujẹ̀ṣà; a o ni fi ọ̀ ṣàwátí laarin awọn ọniyan (eniyan). Ulọsiwaju (ilọsiwaju), ure (ire), ati ubukun (ibunkun) yio jẹ́ tìrẹ. 🏾W* – Wa ri ba ti ṣe, wa r’ọna gbe gba. 🏾Y* – Yara ibukun, ire, ati ayo ailopin loo ma ba ọ gbe titi ọjọ aye rẹ…… _🏾AMIN, L’AṢẸ EDUMARE.*_ _*IRE O!*_ _🏳Ìwọ naa fi ranṣẹ si awon olólùfẹ́ rẹ. Bẹe ni, o le fi ránṣẹ si emi naa ti moba wa lara àwọn olólùfẹ́ rẹ._ — Sent from my Blog http://ift.tt/1scst35

NI ODUN 2017 adura MI si o ni wipe:

🏾A* – Alaafia ni fun ọ.

🏾B* – Buburu kan ki yio
ṣsubú lu ọ.

🏾D* – Dugbẹdugbẹ
ibanujẹ ko ni ja le ọ
l'ori.

🏾E* – Ebi ò ni pa ọ nibi ti
ọdún ku si yi.

🏾E* – Ẹkún, asun'da ko ni jẹ
tirẹ.

🏾F* – Funfun aye rẹ ko ni
d'ibajẹ.

🏾G* – Gunnugun ki ku
l'ewe, wa d'agba
d'arugbo.

🏾GB* – Gbogbo idawole
rẹ a yọrí si rere.

🏾H* – Hausa, Yoruba, Ibo,
gbogbo ẹya ati
eniyan kaakiri
agbaye ni yio kọju
si ọ ṣe ọ loore.

🏾I* – Iwaju, iwaju l'ọpa ẹbiti
rẹ yio ma re si.

🏾J* – Jijade rẹ, wiwole rẹ,
ò ó nik'agbako.

🏾K* – Kukuru abi giga –
ìsorò ko ni jẹ tìrẹ.

🏾L* – Loniloni wa r'aanu
gba.

🏾M*- Mọnamọna ati àra
Ọlọ́run yóò tu àwọn
ọta rẹ ka.

🏾N* – Naira, Euro, Dollar,
Pound, Yen, Yuan,
gbogbo owo ati ọrọ
kaakiri agbaye pẹlu
ọmọ alalubarika ati
alaafia yóò mu ọ
l'ọrẹ, wọn o si fi ile
re ṣe ibugbe.

🏾O* – Ojurere ati aanu yio
ma tọ ọ lẹ́yìn ni ọjọ
aye rẹ̀ gbogbo.

🏾Ọ* – Ọjọ́ ọ̀la rẹ a dara.

🏾P* – Panpẹ aye ò ni mu ọ
t'ọmọtọmọ.

🏾R* – Rere ni agogo aye rẹ
yió ma lu n'igba
gbogbo.

🏾S* – Suuru pẹlu ìtẹ́lọ́rùn
ninu ọrọ at'alaafia
yi o ba ọ́ kalẹ.

🏾Ṣ* – Ṣugbọ́n ati àbáwọn
aye rẹ ti poora loni.

🏾T* – T'ọmọtọmọ, t'ẹbitẹbi,
t'iletile o ni d'ero ẹyin.

🏾U* A kii wátí U ti l'ede
Ekiti Ujẹ̀ṣà; a o ni fi ọ̀
ṣàwátí laarin awọn
ọniyan (eniyan).
Ulọsiwaju (ilọsiwaju),
ure (ire), ati ubukun
(ibunkun) yio jẹ́ tìrẹ.

🏾W* – Wa ri ba ti ṣe, wa
r'ọna gbe gba.

🏾Y* – Yara ibukun, ire, ati
ayo ailopin loo ma
ba ọ gbe titi ọjọ aye
rẹ……

_🏾AMIN, L'AṢẸ EDUMARE.*_

_*IRE O!*_

_🏳Ìwọ naa fi ranṣẹ si
awon olólùfẹ́ rẹ. Bẹe ni, o
le fi ránṣẹ si emi naa ti
moba wa lara àwọn
olólùfẹ́ rẹ._

Sent from my Blog http://ift.tt/1scst35

from Blogger http://ift.tt/2nTDQ6E

via https://www.youtube.com/channel/UCQl_bPHJHwPK–yUeB8Dk1A/videos

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s