Ìṣe Ni Ogún Ìṣe Can anyone remember this poem from primary school? *EVER-GREEN MESSAGES FOR A LASTING LEGACY!* Check this Odunjo ageless Discovery: *ISÉ NI ÒÒGÙN ÌSÉ* Work is the antidote for poverty. *MÚRA SÍ ISÉ RE, ÒRÉ MI* Work hard, my friend. *ISÉ NI A FI Í DI ENI GIGA* Work/Labour is a major tool for elevation. (Aspiring to higher height is fully dependent on hard work). *BÍ A KÒ BÁ RÉNI FÈYÌN TÌ, BÍ ÒLE LÀ Á RÍ* If we do not have anyone to lean on, we appear indolent. *BÍ A KO RÉNI GBÉKÈLÉ* if we do not have anyone to trust (or can depend on). *À A TERA MÓ ISÉ ENI* we simply work harder. *ÌYÁ RE LÈ LÓWÓ LÓWÓ* Your mother may be wealthy. *BÀBÁ SÌ LÈ LÉSIN LÉÈKÀN* Your father may have a ranch full of horses. *BÍ O BÁ GBÓJÚ LÉ WON* if you depend on their riches alone, *O TÉ TÁN NI MO SO FÚN O* you may end up in shame and disgrace, I tell you. *OHUN TÍ A KÒ BA JÌYÀ FÚN* whatever gain one does not work hard to earn. *KÌ Í LÈ TÓJÓ* usually does not last. *OHUN TÍ A BÁ FARA SISÉ FÚN* whatever gain one seriously Laboured for, *NÍ Í PÉ LÓWÓ ENI* is the one that lasts in one’s hands (while in one’s possession). *APÁ LARÁ* the arm is a relative *ÌGÙNPÁ NÌYEKAN* the elbow is a sibling. *BÍ AYÉ N FÉ O LÓNÌÍ* YOU may be loved by *all* today. *BÍ O BÁ LÓWÓ LÓWÓ* It is when you have money, *NI WON Á MÁA FÉ O LÓLA* that they will love you again tomorrow. *TÀBÍ TÍ O BÁ WÀ NÍ IPÒ ÀTÀTÀ* or when you are in a high or respectable position, *AYÉ Á YÉ O SÍ TÈRÍN-TÈRÍN* All will honour you with cheers and smiles. *JÉ KÍ O DI ENI TI N RÁÁGÓ* wait till you become poor or a struggler, *KÍ O RÍ BÁYÉ TI Í YINMÚ SINI* and you will see how all grimace at you as they pass you by. *ÈKÓ SÌ TÚN N SONI Í DÒGÁ* Education also elevates/promotes to higher positions. *MÚRA KÍ O KÓ O DÁRADÁRA* work hard to acquire good education. *BÍ O SÌ RÍ ÒPÒ ÈNÌYÀN* and if you see a lot of people, *TÍ WÓN N FI ÈKÓ SE ÈRÍN RÍN* making Education a laughing stock. *DÁKUN MÁ SE FARA WÉ WON* please do not emulate or keep their company. *ÌYÀ N BÒ FÓMO TÍ KÒ GBÓN* suffering is lying in wait for an unserious kid. *EKÚN N BE FÓMO TÓ N SÁ KIRI* sorrow is in the reserve for a truant kid. *MÁ FÒWÚRÒ SERÉ, ÒRÉ MI* Never toy with your early years, my friend. *MÚRA SÍSÉ, OJÓ N LO* Work harder; time and tide wait for no one. Let’s pass it on to our children and friends. Original work by *J.F Odunjo* — Sent from my Blog http://ift.tt/1scst35

Can anyone remember this poem from primary school?

*EVER-GREEN MESSAGES FOR A LASTING LEGACY!*

Check this Odunjo ageless Discovery:

*ISÉ NI ÒÒGÙN ÌSÉ*
Work is the antidote for poverty.

*MÚRA SÍ ISÉ RE, ÒRÉ MI*
Work hard, my friend.

*ISÉ NI A FI Í DI ENI GIGA*
Work/Labour is a major tool for elevation.
(Aspiring to higher height is fully dependent on hard work).

*BÍ A KÒ BÁ RÉNI FÈYÌN TÌ, BÍ ÒLE LÀ Á RÍ*
If we do not have anyone to lean on, we appear indolent.

*BÍ A KO RÉNI GBÉKÈLÉ*
if we do not have anyone to trust (or can depend on).

*À A TERA MÓ ISÉ ENI*
we simply work harder.

*ÌYÁ RE LÈ LÓWÓ LÓWÓ*
Your mother may be wealthy.

*BÀBÁ SÌ LÈ LÉSIN LÉÈKÀN*
Your father may have a ranch full of horses.

*BÍ O BÁ GBÓJÚ LÉ WON*
if you depend on their riches alone,

*O TÉ TÁN NI MO SO FÚN O*
you may end up in shame and disgrace, I tell you.

*OHUN TÍ A KÒ BA JÌYÀ FÚN*
whatever gain one does not work hard to earn.

*KÌ Í LÈ TÓJÓ*
usually does not last.

*OHUN TÍ A BÁ FARA SISÉ FÚN*
whatever gain one seriously Laboured for,

*NÍ Í PÉ LÓWÓ ENI*
is the one that lasts in one's hands (while in one's
possession).

*APÁ LARÁ*
the arm is a relative

*ÌGÙNPÁ NÌYEKAN*
the elbow is a sibling.

*BÍ AYÉ N FÉ O LÓNÌÍ*
YOU may be loved by *all* today.

*BÍ O BÁ LÓWÓ LÓWÓ*
It is when you have money,

*NI WON Á MÁA FÉ O LÓLA*
that they will love you again tomorrow.

*TÀBÍ TÍ O BÁ WÀ NÍ IPÒ ÀTÀTÀ*
or when you are in a high or respectable position,

*AYÉ Á YÉ O SÍ TÈRÍN-TÈRÍN*
All will honour you with cheers and smiles.

*JÉ KÍ O DI ENI TI N RÁÁGÓ*
wait till you become poor or a struggler,

*KÍ O RÍ BÁYÉ TI Í YINMÚ SINI*
and you will see how all grimace at you as they pass you by.

*ÈKÓ SÌ TÚN N SONI Í DÒGÁ*
Education also elevates/promotes to higher positions.

*MÚRA KÍ O KÓ O DÁRADÁRA*
work hard to acquire good education.

*BÍ O SÌ RÍ ÒPÒ ÈNÌYÀN*
and if you see a lot of people,

*TÍ WÓN N FI ÈKÓ SE ÈRÍN RÍN*
making Education a laughing stock.

*DÁKUN MÁ SE FARA WÉ WON*
please do not emulate or keep their company.

*ÌYÀ N BÒ FÓMO TÍ KÒ GBÓN*
suffering is lying in wait for an unserious kid.

*EKÚN N BE FÓMO TÓ N SÁ KIRI*
sorrow is in the reserve for a truant kid.

*MÁ FÒWÚRÒ SERÉ, ÒRÉ MI*
Never toy with your early years, my friend.

*MÚRA SÍSÉ, OJÓ N LO*
Work harder; time and tide wait for no one.

Let’s pass it on to our children and friends.

Original work by *J.F Odunjo*

Sent from my Blog http://ift.tt/1scst35

from Blogger http://ift.tt/2mvqZ5R

via https://www.youtube.com/channel/UCQl_bPHJHwPK–yUeB8Dk1A/videos

Advertisements

Leave a Reply

Fill in your details below or click an icon to log in:

WordPress.com Logo

You are commenting using your WordPress.com account. Log Out /  Change )

Google+ photo

You are commenting using your Google+ account. Log Out /  Change )

Twitter picture

You are commenting using your Twitter account. Log Out /  Change )

Facebook photo

You are commenting using your Facebook account. Log Out /  Change )

w

Connecting to %s